• P.O Box 16, Oke-Amola, Ikirun
  • 08033895291, 08052485673
  • P.O Box 16, Oke-Amola, Ikirun
  • 08033895291, 08052485673

Statement of Faith

STATEMENT OF FAITH (ENGLISH)

I believe in God the Father Almighty, Maker of Heaven and Earth. I believe in Jesus Christ, his only son our Lord, who was conceived by the Holy Ghost, Born of the Virgin Mary; Suffered under Pontius Pilate; was crucified, dead and was buried. He descended in grave, the Third day; He rose again from the dead, He ascended into Heaven and Sited at the right hand of God the father Almighty, from thence he will come to judge the quick and the dead.

I believe in the Holy Ghost; The Holy Church of God communion of Saint, the forgiveness of sin; the resurrection of the body and life everlasting.

Amen.

STATEMENT OF FAITH (YORUBA)

Mo gba Olorun Baba Olodumare gbo, Eleda Orun on Aye. Mo gba Jesu Kristi Gbo; omo Re nikansoso Oluwa wa, Eni ti a fi Emi Mimo Loyun, Eni ti A bi ninu Maria wundia, Eni to jiya lowo Pontu Pilatu ; Eni ti a Kanmo Agbelebu, Eni ti oku, ti a si sin, O sokale re ipo oku; ni ojo keta, O jinda kuro ninu oku; o re oke Orun, O si joko lowo otun Olorun Baba Olodumare, Nibe ni yio ti wa se Idajo aye oun oku.

Mo gba Emi Mimo gbo, Ijo Mimo eniyan Olorun, Idapo awon eniyan mimo Idariji ese, ajinde ara ni isa oku ati iye ti ko nipekun.

Amin

Translate »
Open chat
Powered by